Jeremiah 45:4 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
“Èmi ń wó ohun tí mo kọ́ lulẹ̀, mo sì ń tu ohun tí mo gbìn, bẹ́ẹ̀ ni ọ̀rọ̀ gbogbo ilẹ̀ náà rí.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Bayi ni ki iwọ sọ fun u, Oluwa wi bayi; pe, Wò o, eyi ti emi ti kọ́, li emi o wo lulẹ, ati eyi ti emi ti gbìn li emi o fà tu, ani gbogbo ilẹ yi.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
OLÚWA wí pé sọ èyí fún un, “Èyí ni Ọlọ́run sọ: ‘Èmi yóò sí ipò àwọn ohun tí mo ti kọ àti pé: Èmi yóò wú àwọn nǹkan tí mo gbìn sí orí ilẹ̀ náà.