Jeremiah 46:12 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Àwọn orílẹ̀ èdè ti gbọ́ nípa ìtìjú yín, igbe yín ti gba ayé kan; nítorí àwọn ọmọ ogun ń rọ́ lu ara wọn; gbogbo wọn sì ṣubú papọ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Awọn orilẹ-ède ti gbọ́ itiju rẹ, igbe rẹ si ti kún ilẹ na: nitori alagbara ọkunrin ti kọsẹ lara alagbara, ati awọn mejeji si jumọ ṣubu pọ̀.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn orílẹ̀ èdè yóò gbọ́ nípa ìtìjú rẹ, igbe rẹ yóò kún gbogbo ayé. Jagunjagun yóò máa ṣubú lu ara wọn lórí rẹ, àwọn méjèèjì yóò sì dìjọ ṣubú papọ̀.”

Recommended Reading