Jeremiah 46:14 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ó ní, “Ẹ kéde ní Ijipti, ẹ polongo ní Migidoli, ní Memfisi ati ní Tapanhesi. Ẹ wí pé, ‘Ẹ gbáradì kí ẹ sì múra sílẹ̀, nítorí ogun yóo run yín yíká.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ẹ sọ ọ ni Egipti, ki ẹ si jẹ ki a gbọ́ ni Migdoli, ẹ si jẹ ki a gbọ́ ni Nofu ati Tafanesi: ẹ wipe, duro lẹsẹsẹ, ki o si mura, nitori idà njẹrun yi ọ kakiri.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
“Kéde èyí ní Éjíbítì, sì sọ ọ́ ní Nígídò, sọ ọ́ ní Mémífísì àti Táfánésì: ‘Dúró sí àyè rẹ kí o sì múra sílẹ̀, nítorí pé idà náà ń pa àwọn tí ó yí ọ ká.’