Jeremiah 46:15 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Kí ló dé tí àwọn akọni yín kò lè dúró? Wọn kò lè dúró nítorí pé OLUWA ni ó bì wọ́n ṣubú.’
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ẽṣe ti a fi gbá awọn akọni rẹ lọ? nwọn kò duro, nitori Oluwa le wọn.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Èéṣe tí àwọn akọni rẹ fi ṣubú? Wọn kò ní le dìde dúró, nítorí OLÚWA yóò tì wọ́n ṣubú.