Jeremiah 46:20 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ijipti dàbí ọmọ mààlúù tí ó lẹ́wà, ṣugbọn irù kan, tí ó ti ìhà àríwá fò wá, ti bà lé e.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ẹgbọrọ malu ti o dara pupọ ni Egipti, lõtọ, iparun de, o de lati ariwa!
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
“Ẹgbọ̀rọ̀ abo màlúù tó lẹ́wà ní Éjíbítì ṣùgbọ́n eṣinṣin tí yóò le ń bọ̀ láti àríwá.