Jeremiah 46:22 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ó ń dún bí ejò tí ó ń sálọ; nítorí pé àwọn ọ̀tá rẹ̀ ń bọ̀ tagbára tagbára, wọ́n ń kó àáké bọ̀ wá bá a, bí àwọn tí wọn ń gé igi.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ohùn inu rẹ̀ yio lọ gẹgẹ bi ti ejo; nitori nwọn o lọ pẹlu agbara; pẹlu àkeke lọwọ ni nwọn tọ̀ ọ wá bi awọn akégi.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Éjíbítì yóò pòṣé bí ejò tí ń sá bí ọmọ ogun ṣe ń tọ̀ ọ́ wá pẹ̀lú agbára. Wọn ó tọ̀ ọ́ wá pẹ̀lú àáké, gẹ́gẹ́ bí i ti agégi.