Jeremiah 46:4 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ẹ̀yin ẹlẹ́ṣin, ẹ di ẹṣin yín ní gàárì, kí ẹ sì gùn wọ́n. Ẹ dúró ní ipò yín, pẹlu àṣíborí lórí yín. Ẹ pọ́n àwọn ọ̀kọ̀ yín, kí ẹ gbé ihamọra irin yín wọ̀!’ ”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ẹ di ẹṣin ni gãrì; ẹ gùn wọn, ẹnyin ẹlẹṣin, ẹ duro lẹsẹsẹ ninu akoro nyin; ẹ dan ọ̀kọ, ẹ wọ ẹwu irin.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Di ẹṣin ní gàárì, kí ẹ sì gùn ún. Ẹ dúró lẹ́sẹsẹ pẹ́lú àsíborí yín! Ẹ dán ọ̀kọ̀ wò, kí ẹ sì wọ ẹ̀wù irin.