Jeremiah 46:6 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Àwọn tí ẹsẹ̀ wọn yá nílẹ̀ kò lè sálọ, bẹ́ẹ̀ ni àwọn ọmọ ogun kò lè sá àsálà. Ìhà àríwá, lẹ́bàá odò Yufurate, ni wọ́n tí fẹsẹ̀ kọ, tí wọ́n sì ṣubú.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ẹni ti o yara, kì yio salọ, alagbara ọkunrin kì yio si sala: ni iha ariwa lẹba odò Ferate ni nwọn o kọsẹ̀, nwọn o si ṣubu.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
“Ẹni tí ó yára kì yóò le sálọ, tàbí alágbára kò ní lè sá àsálà. Ní Gúṣù ní ibi odò Ẹ́fúrétà wọn yóò kọsẹ̀, wọn yóò sì ṣubú.