Jeremiah 46:9 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ó yá, ẹṣin, ẹ gbéra, kí kẹ̀kẹ́ ogun máa sáré kíkankíkan! Kí àwọn ọmọ ogun máa nìṣó, àwọn ọmọ ogun Etiopia ati Puti, tí wọ́n mọ asà á lò, àwọn ọmọ ogun Ludi, tí wọ́n mọ ọfà á ta dáradára.’ ”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ẹ goke wá, ẹnyin ẹṣin, ẹ si sare kikan, ẹnyin kẹ̀kẹ; ki awọn alagbara si jade wá; awọn ara Etiopia, ati awọn ara Libia, ti o ndi asà mu; ati awọn ara Lidia ti nmu ti o nfa ọrun.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ẹ gòkè wá ẹ̀yin ẹṣin, ẹ sì sáré kíkankíkan ẹ̀yin kẹ̀kẹ́. Kí àwọn alágbára túbọ̀ tẹ̀síwájú, ẹ̀yin ọkùnrin Kúṣì àti Pútì tí ń gbé ọ̀kọ̀; àti ẹ̀yin ọkùnrin Lìdíà tí ń fa ọrun.