Jeremiah 47:5 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ìbànújẹ́ ti dé bá Gasa, Aṣikeloni ti parun. Ẹ̀yin tí ẹ kù lára àwọn ọmọ Anakimu, ẹ óo ti fi ìbànújẹ́ ṣá ara yín lọ́gbẹ́ pẹ́ tó?
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ipári de si Gasa, Aṣkeloni ti dahoro, pẹlu iyokù afonifoji wọn: iwọ o ti ṣa ara rẹ lọgbẹ pẹ to?
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Gásà yóò fá irun orí rẹ̀ nínú ọ̀fọ̀. A ó pa Áṣíkélónì lẹ́nu mọ́; ìyókù ní pẹ̀tẹ́lẹ̀, ìwọ yóò ti ṣá ara rẹ lọ́gbẹ́ pẹ́ tó?