Jeremiah 47:7 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ṣugbọn idà OLUWA ṣe lè dákẹ́ jẹ́ẹ́, nígbà tí Oluwa fún un ní iṣẹ́ láti ṣe? OLUWA ti pàṣẹ fún un láti kọlu Aṣikeloni, ati àwọn ìlú etí òkun.”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ṣugbọn bawo li o ti ṣe le gbe jẹ, nigbati Oluwa ti paṣẹ fun u si Aṣkeloni, ati si ebute okun, nibẹ li o ti ran a lọ!
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ṣùgbọ́n báwo ni yóò ṣe sinmi, nígbà tí OLÚWA ti pàṣẹ fún un, nígbà tí ó ti pa á láṣẹ láti dojúkọ Áṣíkélónì àti agbégbé rẹ̀.”