Jeremiah 48:13 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Kemoṣi yóo di ohun ìtìjú fún Moabu, gẹ́gẹ́ bí Bẹtẹli, tí Israẹli gbójú lé, ṣe di ohun ìtìjú fún Israẹli.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Moabu yio si tiju nitori Kemoṣi, gẹgẹ bi ile Israeli ti tiju nitori Beteli, igbẹkẹle wọn.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nígbà náà Móábù yóò sì tú u nítorí kémósì, bí ojú ti í ti ilé Ísírẹ́lì nígbà tí ó gbẹ́kẹ̀lé Bétélì.