Jeremiah 48:24 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Kerioti, Bosira, ati gbogbo àwọn ìlú ilẹ̀ Moabu, ati àwọn tí wọ́n wà nítòsí, ati àwọn tí wọ́n wà lókèèrè.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ati sori Kerioti, ati sori Bosra, ati sori gbogbo ilu ilẹ Moabu, lokere ati nitosi.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
sórí Kéríótì àti Bóásì, sórí gbogbo ìlú Móábù, nítòsí àti ní ọ̀nà jínjìn.