Jeremiah 48:26 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
OLUWA ní, “Ẹ rọ Moabu lọ́tí yó, nítorí pé ó gbéraga sí OLUWA; kí ó lè máa yíràá ninu èébì rẹ̀, a óo sì fi òun náà ṣẹ̀sín.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ẹ mu u yo bi ọmuti: nitori o gberaga si Oluwa: Moabu yio si ma pàfọ ninu ẽbi rẹ̀; on pẹlu yio si di ẹni-ẹ̀gan.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
“Ẹ jẹ́ kí a mú u mutí nítorí ó kó ìdọ̀tí bá OLÚWA, jẹ́ kí Móábù pàfọ̀ nínú èébì rẹ̀, kí ó di ẹni ẹ̀gàn.