Jeremiah 48:31 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Nítorí náà, ni mo ṣe ń sọkún tẹ̀dùntẹ̀dùn, tí mò ń kígbe sókè nítorí Moabu tí mo sì ń ṣọ̀fọ̀ nítorí àwọn ará Kiri Heresi.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitorina ni emi o hu fun Moabu, emi o si kigbe soke fun gbogbo Moabu, lori awọn ọkunrin Kirheresi li a o ṣọ̀fọ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nítorí náà, mo pohùnréré ẹkún lórí Móábù fún àwọn ará Móábù ni mo kígbe lóhùn rara Mo kẹ́dùn fún àwọn ọkùnrin Kíháráṣè.