Jeremiah 48:34 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
“Heṣiboni ati Eleale kígbe sókè, igbe wọn sì dé Jahasi láti Soari, ó dé Horonaimu ati Egilati Ṣeliṣiya. Àwọn odò Nimrimu pàápàá ti gbẹ.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Lati igbe Heṣboni de Eleale, de Jahasi, ni nwọn fọ ohùn wọn, lati Soari de Horonaimu, ti iṣe ẹgbọrọ malu ọlọdun mẹta, nitori omi Nimrimu pẹlu yio dahoro.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
“Ohùn igbe wọn gòkè láti Hésíbónì dé Élíà àti Jásì láti Sóà títí dé Hórónáímù àti Éjíbítì Sélíáyà, nítorí àwọn omi Nímírímù pẹ̀lú ti gbẹ