Jeremiah 48:36 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
“Nítorí náà ni mo ṣe ń dárò Moabu ati àwọn ará Kiri Heresi bí ẹni fi fèrè kọ orin arò nítorí pé gbogbo ọrọ̀ tí wọ́n kó jọ ti ṣègbé.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitorina ni ọkàn mi ró fun Moabu bi fère, ọkàn mi yio si ró bi fere fun awọn ọkunrin Kirheresi: nitori iṣura ti o kojọ ṣegbe.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
“Nítorí náà ọkàn mi ró fún Móábù bí fèrè oró Híhárésétì ìṣúra ńlá tí wọ́n kójọ ṣègbé.