Jeremiah 48:37 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Gbogbo wọn ti fá irun orí ati irùngbọ̀n wọn; wọ́n ti fi abẹ ya gbogbo ọwọ́ wọn, wọ́n sì lọ́ aṣọ ọ̀fọ̀ mọ́ ìbàdí.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitori gbogbo ori ni yio pá, ati gbogbo irungbọn li a o ke kù: ọgbẹ yio wà ni gbogbo ọwọ, ati aṣọ-ọ̀fọ ni ẹgbẹ mejeji.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Gbogbo orí mi ni ó pá, gbogbo irungbọ̀n ni a gé kúrò, gbogbo ọwọ́ ni a ṣá lọ́gbẹ́, àti aṣọ ọ̀fọ̀ ní gbogbo ẹ̀gbẹ́.