Jeremiah 48:41 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ogun yóo kó àwọn ìlú Moabu, wọn óo sì gba àwọn ibi ààbò rẹ̀. Ní ọjọ́ náà, ọkàn àwọn ọmọ ogun Moabu yóo dàbí ọkàn obinrin tí ó ń rọbí,
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
A kó Kerioti, a si kó awọn ilu olodi, ati ọkàn awọn akọni Moabu li ọjọ na yio dabi ọkàn obinrin ninu irọbi rẹ̀.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Koríko kan yóò di kíkó àti àwọn ìlú olódì. Ní ọjọ́ náà ọkàn akọni Móábù yóò dàbí ọkàn obìnrin tí ó ń rọbí.