Jeremiah 48:42 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Moabu yóo parun, kò ní jẹ́ orílẹ̀-èdè mọ́, nítorí pé ó ṣe ìgbéraga sí OLÚWA.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
A o si pa Moabu run lati má jẹ orilẹ-ède, nitoripe o ti gberaga si Oluwa.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
A ó pa Móábù run gẹ́gẹ́ bí orílẹ̀ èdè nítorípé ó gbéraga sí OLÚWA.