Jeremiah 48:46 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ẹ̀yin ará Moabu, ẹ gbé! Ó ti parí fun yín, ẹ̀yin ọmọ Kemoṣi, nítorí a ti kó àwọn ọmọkunrin yín lẹ́rú, a ti kó àwọn ọmọbinrin yín lọ sí ìgbèkùn.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Egbe ni fun ọ, iwọ Moabu! orilẹ-ède Kemoṣi ṣegbe: nitori a kó awọn ọkunrin rẹ ni igbekun, ati awọn ọmọbinrin rẹ ni igbekun.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ègbé ní fún ọ Móábù! Wọn yóò sì kó àwọn ọmọkùnrin yín lọ sí ilẹ̀ àjèjì àti àwọn ọmọbìnrin yín lọ sí ìgbékùn.