Jeremiah 48:5 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Bí wọn tí ń gun òkè Luhiti, bẹ́ẹ̀ ni wọ́n ń sọkún, nítorí pé nígbà tí wọn tí ń lọ níbi ẹsẹ̀ òkè Horonaimu, ni wọ́n tí ń gbọ́ igbe ìparun; pé,
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitori ẹkun tẹle ẹkun ni ọ̀na igoke lọ si Luhiti: nitori ni ọ̀na isọkalẹ Horonaimu a gbọ́ imi-ẹ̀dun, igbe iparun, pe:
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Wọ́n gòkè lọ sí Lúhítì, wọ́n ń sunkún kíkorò bí wọ́n ti ń lọ; ní ojú ọ̀nà sí Horonáímù igbe ìrora ìparun ni à ń gbọ́ lọ.