Jeremiah 49:11 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Fi àwọn ọmọ rẹ, aláìníbaba sílẹ̀, n óo pa wọ́n mọ́ láàyè, sì jẹ́ kí àwọn opó rẹ gbẹ́kẹ̀lé mi.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Fi awọn ọmọ alainibaba rẹ silẹ, emi o si pa wọn mọ lãye; ati ki awọn opó rẹ ki o gbẹkẹle mi.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Fi àwọn ọmọ aláìní baba sílẹ̀ èmi yóò dábòbo ẹ̀mí wọn. Àwọn opó rẹ gan an lè gbékẹ̀lẹ́ mi.”