Jeremiah 49:15 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Nítorí pé n óo sọ ọ́ di kékeré láàrin àwọn orílẹ̀-èdè, o óo sì di yẹpẹrẹ, láàrin àwọn ọmọ eniyan.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitori, wò o, emi o ṣe ọ ni ẹni-kekere lãrin awọn orilẹ-ède, ẹni-ẹgan lãrin awọn enia.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
“Ní báyìí, èmi yóò sọ ọ́ di kékeré láàrin orílẹ̀ èdè gbogbo; ẹni ẹ̀gàn láàrin àwọn ènìyàn.