Jeremiah 49:26 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Àwọn ọdọmọkunrin Damasku yóo ṣubú ní gbàgede rẹ̀ ní ọjọ́ náà, gbogbo àwọn ọmọ ogun ibẹ̀ yóo sì parun ni; Èmi OLUWA àwọn ọmọ ogun ni mo sọ bẹ́ẹ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitorina awọn ọdọmọkunrin rẹ̀ yio ṣubu ni ita rẹ̀, ati gbogbo awọn ọkunrin ogun ni a o ke kuro li ọjọ na, li Oluwa awọn ọmọ-ogun wi.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Lóòtọ́, àwọn ọ̀dọ́mọkùnrin rẹ yóò ṣubú lójú pópó, gbogbo àwọn ọmọ ogun rẹ yóò pa ẹnu mọ́ ní ọjọ́ náà,” ní OLÚWA àwọn ọmọ ogun wí.