Jeremiah 49:29 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ogun yóo kó àgọ́ wọn ati àwọn ẹran ọ̀sìn wọn lọ, ati àwọn aṣọ àgọ́, ati ohun ìní wọn; Ọ̀tá yóo kó ràkúnmí wọn lọ, àwọn eniyan yóo máa kígbe sí wọn pé, ‘Ìpayà wà ní gbogbo àyíká.’
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Agọ wọn ati agbo-ẹran wọn ni nwọn o kó lọ: nwọn o mu aṣọ agọ wọn fun ara wọn, ati gbogbo ohun-èlo wọn, ati ibakasiẹ wọn; nwọn o si kigbe sori wọn pe, Ẹ̀ru yikakiri!
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àgọ́ wọn àti agbo àgùntàn wọn yóò di gbígbà; ilé wọn yóò di ìsínípò padà pẹ̀lú ẹrù àti ràkúnmí wọn. Àwọn ọkùnrin yóò ké pè wọ́n; ‘Ìparun ní ibi gbogbo.’