Jeremiah 49:31 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ó ní, ‘Ẹ dìde kí ẹ gbógun ti orílẹ̀-èdè tí ó wà ní alaafia, ati láìléwu, ìlú tí ó dá dúró tí kò sì ní ìlẹ̀kùn tabi ọ̀pá ìdábùú ìlẹ̀kùn fún ààbò.’
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Dide, goke lọ sọdọ orilẹ-ède kan ti o wà ni irọra, ti o ngbe li ailewu, li Oluwa wi, ti kò ni ilẹkun ẹnu-bode tabi ikere; ti ngbe fun ara rẹ̀.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
“Dìde kí o sì dojú ìjà kọ orílẹ̀ èdè kan pẹ̀lú ìrọ̀rùn, èyí tí ó dúró pẹ̀lú ìgboyà;” báyìí ní OLÚWA wí. “Orílẹ̀ èdè tí kò ní yálà gbàgede tàbí irin, àwọn ènìyàn re ń dágbé.