Jeremiah 49:33 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Hasori yóo di ibùgbé ajáko, yóo di ahoro títí laelae. Ẹnìkan kò ní gbé ibẹ̀ mọ́, bẹ́ẹ̀ ni ẹnikẹ́ni kò ní dé sibẹ mọ́.”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Hasori yio di ibugbe fun ọ̀wawa, ahoro titi lai: kì o si ẹnikan ti yio joko nibẹ, bẹ̃ni ọmọ enia kan kì yio ṣatipo ninu rẹ̀.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
“Ásọ́rì yóò di ibi ìdọdẹ àwọn akáta, ibi ìkọ̀sílẹ̀ ayérayé, kò sí ẹni tí yóò gbé ní ibẹ̀.”