Jeremiah 49:35 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ó ní, “Wò ó! N óo pa àwọn tafàtafà Elamu, tí wọn jẹ́ orísun agbára wọn,
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Bayi li Oluwa awọn ọmọ-ogun wi; Wò o, emi o ṣẹ́ ọrun Elamu, ti iṣe olori agbara wọn.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Èyí ni ohun tí Ọlọ́run alágbára sọ: “Wò ó, èmi yóò fọ́ ìtẹ̀gùn Élámù, ẹni tí wọ́n sinmi lé nípa agbára.