Jeremiah 49:5 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Wò ó! N óo kó ìpayà bá ọ, láti ọ̀dọ̀ gbogbo àwọn tí wọ́n yí ọ ká; èmi OLUWA Ọlọrun àwọn ọmọ ogun ni mo sọ bẹ́ẹ̀. Gbogbo yín ni yóo fọ́nká, tí olukuluku yóo sì yà sí ọ̀nà tirẹ̀, kò sì ní sí ẹni tí yóo kó àwọn tí ń sá fún ogun jọ.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Wò o, emi o mu ẹ̀ru wá sori rẹ, li Oluwa Ọlọrun awọn ọmọ-ogun wi, lati ọdọ gbogbo awọn wọnni ti o wà yi ọ kakiri; a o si le nyin, olukuluku enia tàra niwaju rẹ̀; ẹnikan kì o si kó awọn ti nsalọ jọ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Èmi yóò mu ẹ̀rù wá lórí rẹ láti ọ̀dọ̀ gbogbo àwọn tó yí ọ ká,” ni OLÚWA wí: