Jeremiah 49:6 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
“Ṣugbọn lẹ́yìn náà, n óo dá ire àwọn ará Amoni pada. Èmi OLUWA ni mo sọ bẹ́ẹ̀.”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ati nikẹhin emi o tun mu igbekun awọn ọmọ Ammoni pada, li Oluwa wi.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
“OLÚWA àwọn ọmọ ogun. Gbogbo yín ni ó lé jáde, kò sì sí ẹnìkan tí yóò dá ìkólọ Ámónì padà,” ni OLÚWA wí.