Jeremiah 49:9 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Bí àwọn tí ń kórè èso àjàrà bá bẹ̀rẹ̀ sí kórè, ṣebí wọn a máa fi èso díẹ̀ díẹ̀ sílẹ̀? Bí àwọn olè bá wọlé lóru, ṣebí ìba ohun tí ó bá wù wọ́n ni wọn yóo kó?
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Bi awọn aka-eso ba tọ̀ ọ wá, nwọn kì o ha kù ẽṣẹ́ eso ajara silẹ? bi awọn ole ba wá li oru, nwọn kì o ha parun titi yio fi tẹ́ wọn lọrùn.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Tí àwọn tí ń ṣa èso bá tọ̀ ọ́ wá; ǹjẹ́ wọn kò ní fi èso díẹ̀ sílẹ̀? Tí olè bá wá ní òru; ǹjẹ́ wọn kò ní kó gbogbo ohun tí wọ́n bá fẹ́?