Jeremiah 5:13 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Àwọn wolii yóo di àgbá òfo; nítorí kò sí ọ̀rọ̀ OLUWA ninu wọn. Bí wọ́n ti wí ni ọ̀rọ̀ yóo rí fún wọn.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Awọn woli yio di ẹfufu, ọ̀rọ kò sì si ninu wọn: bayi li a o ṣe si wọn.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn wòlíì wá dàbí afẹ́fẹ́, ọ̀rọ̀ kò sí nínú wọn. Nítorí náà, jẹ́ kí ohun tí wọ́n bá sọ ṣẹlẹ̀ sí wọn.”