Jeremiah 5:18 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
OLUWA ní, “Ṣugbọn sibẹ, ní gbogbo àkókò yìí, n kò ní pa yín run patapata,
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ṣugbọn li ọjọ wọnnì, li Oluwa wi, emi kì yio ṣe iparun nyin patapata.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
“Ní ọjọ́ wọ̀n-ọn-nì,” ni OLÚWA wí, “Èmi kì yóò pa yín run pátapáta.