Jeremiah 5:26 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
“Àwọn eniyan burúkú wà láàrin àwọn eniyan mi, wọ́n ń dọdẹ eniyan bí ẹni dọdẹ ẹyẹ, wọ́n dẹ tàkúté, wọ́n fi ń mú eniyan.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitori lãrin enia mi ni a ri enia ìka, nwọn wò kakiri, bi biba ẹniti ndẹ ẹiyẹ, nwọn dẹ okùn nwọn mu enia.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
“Láàrin ènìyàn mi ni ìkà ènìyàn wà tí ó wà ní ibùba bí ẹni tí ó ń dẹ ẹyẹ, àti bí àwọn tí ó ń dẹ pàkúté láti mú ènìyàn.