Jeremiah 5:29 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ṣé n kò wá ní jẹ wọ́n níyà fún àwọn nǹkan tí wọ́n ṣe wọnyi? Kí n má gbẹ̀san ara mi, lára irú orílẹ̀-èdè yìí?
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Emi kì yio ha ṣe ibẹwò nitori nkan wọnyi, li Oluwa wi, ẹmi mi kì yio ha gbẹsan lori orilẹ-ède bi eyi?
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Èmi kì yóò ha fi ìyà jẹ wọ́n fún èyí bí?” ni OLÚWA wí. “Èmi kì yóò wá gbẹ̀san ara mi lára orílẹ̀ èdè bí èyí bí?