Jeremiah 5:4 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Nígbà náà ní mo wí lọ́kàn ara mi pé, “Àwọn aláìní nìkan nìwọ̀nyí, wọn kò gbọ́n; nítorí wọn kò mọ ọ̀nà OLUWA, ati òfin Ọlọrun wọn.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Emi si wipe, Lõtọ talaka enia ni awọn wọnyi, nwọn kò ni oye, nitori nwọn kò mọ̀ ọ̀na Oluwa, tabi idajọ Ọlọrun wọn.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Èmi sì rò pé, “talákà ni àwọn yìí wọn kò lóye nítorí pé wọn kò mọ ọ̀nà OLÚWA, àti ohun tí Ọlọ́run wọn ń fẹ́.