Jeremiah 5:9 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ṣé n kò wá ní jẹ wọ́n níyà fún àwọn nǹkan tí wọ́n ṣe wọnyi? Àbí n kò ní gbẹ̀san ara mi lára irú orílẹ̀-èdè yìí?
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Emi kì yio ha ṣe ibẹwo nitori nkan wọnyi? li Oluwa wi, ẹmi mi kì yio ha gbẹsan lara iru orilẹ-ède bi eyi?
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Èmi kì yóò ṣàì fìyà jẹ wọ́n fún èyí?” ni OLÚWA wí. “Èmi kì yóò wá gba ẹ̀san fúnra mi lára irú orílẹ̀ èdè bí èyí bí?