Jeremiah 50:10 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ohun ìní àwọn ará Kalidea yóo di ìkógun; gbogbo àwọn tí wọn yóo kó wọn lẹ́rù ni yóo kó ẹrù ní àkótẹ́rùn, Èmi OLUWA ni mo sọ bẹ́ẹ̀.”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Kaldea yio si di ikogun: gbogbo awọn ti o fi ṣe ikogun ni a o tẹ́ lọrùn, li Oluwa wi.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
A ó dààmú Bábílónì, gbogbo àwọn tó dààmú rẹ yóò sì mú ìfẹ́ wọn sẹ,” ni OLÚWA wí.