Jeremiah 50:14 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
“Ẹ gbógun ti Babiloni yíká, gbogbo ẹ̀yin tafàtafà. Ẹ máa ta á lọ́fà, ẹ má ṣẹ́ ọfà kankan kù, nítorí pé ó ti ṣẹ OLUWA.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ẹ tẹgun si Babeli yikakiri: gbogbo ẹnyin ti nfà ọrun, ẹ tafa si i, ẹ máṣe ṣọ́ ọfa lò, nitoriti o ti ṣẹ̀ si Oluwa.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
“Dúró sí àyè rẹ ìwọ Bábílónì àti gbogbo ẹ̀yin tí ẹ ta ọfà náà. Ẹ ta ọfà náà síi, nítorí ó ti sẹ̀ sí OLÚWA.