Jeremiah 50:18 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Nítorí náà èmi OLUWA àwọn ọmọ ogun, Ọlọrun Israẹli, ni mo sọ pé n óo jẹ ọba Babiloni ati ilẹ̀ rẹ̀ níyà, bí mo ṣe jẹ ọba Asiria níyà.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitorina bayi li Oluwa awọn ọmọ-ogun, Ọlọrun Israeli wi pe, wò o, emi o jẹ ọba Babeli ati ilẹ rẹ̀ niya, gẹgẹ bi emi ti jẹ ọba Assiria niya.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nítorí náà, èyí ni ohun tí OLÚWA Ọlọ́run alágbára Ọlọ́run Ísírẹ́lì wí; “Ǹ ó fi ìyà jẹ Ọba Bábílónì àti ilẹ̀ rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí mo ti ṣe fìyà jẹ Ọba, Ásíríà.