Jeremiah 50:20 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
OLUWA ní, Nígbà tí ó bá yá, tí àkókò bá tó, a óo wá ẹ̀ṣẹ̀ tì ní Israẹli ati Juda; nítorí pé n óo dáríjì àwọn tí mo bá ṣẹ́kù.”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Li ọjọ wọnni, ati li akoko na, li Oluwa wi, a o wá aiṣedẽde Israeli kiri, ṣugbọn kì o si mọ́; ati ẹ̀ṣẹ Juda, a kì o si ri wọn: nitori emi o dariji awọn ti mo mu ṣẹkù.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ní ọjọ́ wọ̀n-ọn-nì,” ni OLÚWA wí, “À ó wá àìṣedéédé ẹ̀ṣẹ̀ Ísírẹ́lì, ṣùgbọ́n a ki yóò rí ìkankan; àti ẹṣẹ Júdà a ki yóò sì rí wọn nítorí èmi yóò dáríjìn àwọn tí ó ṣẹ́kù tí mo dásí.