Jeremiah 50:21 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
OLUWA ní, “Ẹ gbógun ti ilẹ̀ Merataimu, ati àwọn ará Pekodi. Ẹ pa wọ́n, kí ẹ sì run wọ́n patapata. Gbogbo nǹkan tí mo pàṣẹ fun yín ni kí ẹ ṣe. Èmi OLUWA ni mo sọ bẹ́ẹ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Goke lọ si ilẹ ọlọtẹ li ọ̀na meji, ani sori rẹ̀ ati si awọn olugbe ilu Ibẹwo: sọ ọ di ahoro ki o si parun lẹhin wọn, li Oluwa wi, ki o si ṣe gẹgẹ bi gbogbo eyiti emi ti paṣẹ fun ọ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
“Kọlu ilẹ̀ Mérátamù àti àwọn tí ó ń gbé ní Pékódì. Kọlùú pa á, kí o sì párun pátapáta,” ni OLÚWA wí “Ṣe gbogbo ohun tí mo paláṣẹ fún ọ.