Jeremiah 50:25 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Mo ti ṣí ìlẹ̀kùn ilé ìṣúra àwọn nǹkan ìjà yín, mo sì kó àwọn ohun ìjà ibinu yín jáde, nítorí èmi OLUWA Ọlọrun àwọn ọmọ ogun ní iṣẹ́ kan láti ṣe ní ilẹ̀ àwọn ará Kalidea.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Oluwa ti ṣi ile ohun-ijà rẹ̀ silẹ; o si ti mu ohun-elo ikannu rẹ̀ jade: nitori Oluwa, Ọlọrun awọn ọmọ-ogun, ni iṣẹ́ iṣe ni ilẹ awọn ara Kaldea.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
OLÚWA ti kó àwọn ohun èlò ìjà rẹ̀ jáde, nítorí pé OLÚWA Ọlọ́run ọmọ ogun ti ṣiṣẹ́ ní ilẹ̀ Bábílónì.