Jeremiah 50:26 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ẹ gbógun tì í ní gbogbo ọ̀nà, ẹ ṣí àká rẹ̀ sílẹ̀, ẹ kó o jọ bí òkítì ọkà, kí ẹ sì pa á run patapata, ẹ má dá ohunkohun sí ninu rẹ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ẹ wá sori rẹ̀ lati opin gbogbo, ṣi ile iṣura rẹ̀ silẹ: ẹ kó o jọ bi òkiti, ki ẹ si yà a sọtọ fun iparun, ẹ máṣe fi iyokù silẹ fun u!
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ẹ dìde sí láti ilẹ̀ jínjín párun pátapáta láìṣẹ́kù.