Jeremiah 50:27 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ẹ pa gbogbo akọ mààlúù rẹ̀, ẹ fà wọ́n lọ sí ibi tí wọ́n ti ń pa ẹran. Àwọn ará Babiloni gbé, nítorí ọjọ́ wọn ti pé, àní ọjọ́ ìjìyà wọn.”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Pa gbogbo awọn akọ-malu rẹ̀! nwọn o lọ si ibi pipa: ègbe ni fun wọn! nitori ọjọ wọn de, àkoko ibẹwo wọn.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Pa gbogbo àwọn ọ̀dọ́ àgùntàn rẹ̀, jẹ́ kí a kó wọn lọ ibi tí a ó ti pa wọ́n! Ègbé ní fún wọn! Nítorí ọjọ́ wọn dé, àkókò ìbẹ̀wò wọn.