Jeremiah 50:32 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Agbéraga, o óo fẹsẹ̀ kọ, o óo sì ṣubú, kò ní sí ẹni tí yóo gbé ọ dìde. N óo dá iná kan ninu àwọn ìlú rẹ, iná náà yóo sì jó gbogbo àyíká rẹ.”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Agberaga yio kọsẹ, yio si ṣubu, ẹnikan kì o si gbe e dide: emi o si da iná ni ilu rẹ̀, yio si jo gbogbo ohun ti o yi i kakiri.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Onígbéraga yóò kọsẹ̀, yóò sì ṣubú, kì yóò sì sí ẹni tí yóò gbé dìde. Èmi yóò tan iná ní ìlú náà, èyí tí yóò sì jo run.”