Jeremiah 50:37 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Idà ni yóo pa àwọn ẹṣin wọn, ati àwọn kẹ̀kẹ́ ogun wọn, idà ni yóo pa gbogbo àwọn àjèjì ọmọ ogun tí wọ́n wà láàrin wọn, Kí wọ́n lè di obinrin! Idà ni yóo fọ́ àwọn ilé ìṣúra wọn, kí wọ́n lè di ìkógun!
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Idà lori awọn ẹṣin rẹ̀, ati lori awọn kẹ̀kẹ ati lori gbogbo awọn àjeji enia ti o wà lãrin rẹ̀; nwọn o si di obinrin: idà lori iṣura rẹ̀; a o si kó wọn lọ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Idà lórí àwọn kẹ̀kẹ́ ẹṣin rẹ̀ àti àwọn àjòjì nínú ẹgbẹ́ rẹ̀. Wọn yóò di obìnrin. Idà lórí àwọn ohun ìṣura rẹ̀!