Jeremiah 50:38 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ọ̀dá yóo dá ní ilẹ̀ wọn, kí àwọn odò wọn lè gbẹ! Nítorí pé ilẹ̀ tí ó kún fún ère ni, wọ́n sì kúndùn ìbọ̀rìṣà.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ọda lori omi odò rẹ̀; nwọn o si gbẹ: nitori ilẹ ere fifin ni, nwọn si nṣogo ninu oriṣa wọn.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ilẹ̀ gbígbẹ lórí omi rẹ̀; yóò sì gbẹ. Nítorí pé ó jẹ́ ilẹ̀ àwọn ère, àwọn ère tí yóò ya òmùgọ̀ pẹ̀lú ẹ̀rù.