Jeremiah 50:4 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
“Nígbà tí àkókò bá tó, àwọn ọmọ Israẹli ati àwọn ọmọ Juda, yóo jọ wá pẹlu ẹkún, wọn yóo máa wá OLUWA Ọlọrun wọn.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Li ọjọ wọnni ati li àkoko na, li Oluwa wi, awọn ọmọ Israeli yio jumọ wá, awọn, ati awọn ọmọ Juda, nwọn o ma lọ tẹkúntẹkún: nwọn o lọ, nwọn o si ṣafẹri Oluwa Ọlọrun wọn.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
“Ní ọjọ́ wọ̀nyí àti ní àkókò náà,” ni OLÚWA wí, “Àwọn ọmọ Ísírẹ́lì yóò jùmọ̀ wá, àwọn, àti àwọn ọmọ Júdà, wọn yóò lọ pẹ̀lú ẹkún láti ṣàfẹ́ri OLÚWA Ọlọ́run wọn